-
Jẹ́nẹ́sísì 45:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kí o máa gbé ilẹ̀ Góṣénì,+ kí o lè wà nítòsí mi, ìwọ, àwọn ọmọ rẹ, àwọn ọmọ ọmọ rẹ, àwọn agbo ẹran rẹ, àwọn ọ̀wọ́ ẹran rẹ àti gbogbo ohun tí o ní.
-