Jẹ́nẹ́sísì 41:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Lẹ́yìn náà, Fáráò sọ Jósẹ́fù ní Safenati-pánéà, ó sì fún un ní Ásénátì+ ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* pé kó fi ṣe aya. Jósẹ́fù wá bẹ̀rẹ̀ sí í bójú tó* ilẹ̀ Íjíbítì.+
45 Lẹ́yìn náà, Fáráò sọ Jósẹ́fù ní Safenati-pánéà, ó sì fún un ní Ásénátì+ ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* pé kó fi ṣe aya. Jósẹ́fù wá bẹ̀rẹ̀ sí í bójú tó* ilẹ̀ Íjíbítì.+