Jẹ́nẹ́sísì 34:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ nígbà tí àwọn ọmọ Jékọ́bù gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀, wọ́n pa dà wálé láti inú pápá lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. Inú wọn ò dùn rárá, inú sì bí wọn gidigidi, torí ó ti dójú ti Ísírẹ́lì bó ṣe bá ọmọ Jékọ́bù+ sùn, ohun tí kò yẹ kó ṣẹlẹ̀.+
7 Àmọ́ nígbà tí àwọn ọmọ Jékọ́bù gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀, wọ́n pa dà wálé láti inú pápá lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀. Inú wọn ò dùn rárá, inú sì bí wọn gidigidi, torí ó ti dójú ti Ísírẹ́lì bó ṣe bá ọmọ Jékọ́bù+ sùn, ohun tí kò yẹ kó ṣẹlẹ̀.+