-
Mátíù 24:37-39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Torí bí àwọn ọjọ́ Nóà ṣe rí gẹ́lẹ́+ ló máa rí tí Ọmọ èèyàn bá ti wà níhìn-ín.*+ 38 Torí bó ṣe rí ní àwọn ọjọ́ yẹn ṣáájú Ìkún Omi, wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, a sì ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ 39 wọn ò fiyè sí i títí Ìkún Omi fi dé, tó sì gbá gbogbo wọn lọ,+ bẹ́ẹ̀ ló máa rí tí Ọmọ èèyàn bá ti wà níhìn-ín.
-