Jẹ́nẹ́sísì 7:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó run gbogbo ohun alààyè tó wà ní ayé, títí kan èèyàn àti ẹran, ẹran tó ń rákò àti àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run. Gbogbo wọn pátá ló pa run ní ayé;+ Nóà àti àwọn tí wọ́n jọ wà nínú áàkì nìkan ló yè é.+ 2 Pétérù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ìyẹn la sì fi pa ayé ìgbà yẹn run nígbà tí ìkún omi bò ó mọ́lẹ̀.+
23 Ó run gbogbo ohun alààyè tó wà ní ayé, títí kan èèyàn àti ẹran, ẹran tó ń rákò àti àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run. Gbogbo wọn pátá ló pa run ní ayé;+ Nóà àti àwọn tí wọ́n jọ wà nínú áàkì nìkan ló yè é.+