ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 7:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì, ní ọdún tí Nóà pé ẹni ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọdún, ọjọ́ yẹn ni gbogbo orísun omi ya, àwọn ibodè omi ọ̀run sì ṣí.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 7:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ó run gbogbo ohun alààyè tó wà ní ayé, títí kan èèyàn àti ẹran, ẹran tó ń rákò àti àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run. Gbogbo wọn pátá ló pa run ní ayé;+ Nóà àti àwọn tí wọ́n jọ wà nínú áàkì nìkan ló yè é.+

  • Mátíù 24:38, 39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Torí bó ṣe rí ní àwọn ọjọ́ yẹn ṣáájú Ìkún Omi, wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu, àwọn ọkùnrin ń gbéyàwó, a sì ń fa àwọn obìnrin fún ọkọ, títí di ọjọ́ tí Nóà wọ ọkọ̀ áàkì,+ 39 wọn ò fiyè sí i títí Ìkún Omi fi dé, tó sì gbá gbogbo wọn lọ,+ bẹ́ẹ̀ ló máa rí tí Ọmọ èèyàn bá ti wà níhìn-ín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́