ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 23:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Sérà kú sí Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì,+ ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Ábúráhámù wá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀, ó sì ń sunkún nítorí Sérà.

  • Jẹ́nẹ́sísì 23:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Lẹ́yìn náà, Ábúráhámù sin Sérà ìyàwó rẹ̀ sínú ihò tó wà ní Mákípẹ́là níwájú Mámúrè, ìyẹn ní Hébúrónì, ní ilẹ̀ Kénáánì.

  • Jẹ́nẹ́sísì 25:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ísákì àti Íṣímáẹ́lì ọmọ rẹ̀ sin ín sí ihò Mákípẹ́là lórí ilẹ̀ Éfúrónì ọmọ Sóhárì, ọmọ Hétì, tó wà níwájú Mámúrè,+ 10 ilẹ̀ tí Ábúráhámù rà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hétì. Ibẹ̀ ni wọ́n sin Ábúráhámù sí, pẹ̀lú Sérà+ ìyàwó rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́