Jẹ́nẹ́sísì 35:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó yá, Jékọ́bù dé ibi tí Ísákì bàbá rẹ̀ wà ní Mámúrè,+ ní Kiriati-ábà, ìyẹn Hébúrónì, níbi tí Ábúráhámù àti Ísákì pẹ̀lú ti gbé rí bí àjèjì.+ Nọ́ńbà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì.
27 Nígbà tó yá, Jékọ́bù dé ibi tí Ísákì bàbá rẹ̀ wà ní Mámúrè,+ ní Kiriati-ábà, ìyẹn Hébúrónì, níbi tí Ábúráhámù àti Ísákì pẹ̀lú ti gbé rí bí àjèjì.+
22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì.