Àìsáyà 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìkéde nípa Tírè:+ Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+ Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀. A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+
23 Ìkéde nípa Tírè:+ Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+ Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀. A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+