Jóṣúà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 gbogbo àwọn tó ń gbé agbègbè olókè láti Lẹ́bánónì+ lọ dé Misirefoti-máímù;+ àti gbogbo àwọn ọmọ Sídónì.+ Mo máa lé wọn kúrò* níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Kí o ṣáà rí i pé o pín in fún Ísírẹ́lì pé kó jẹ́ ogún wọn, bí mo ṣe pa á láṣẹ fún ọ.+ Máàkù 7:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó gbéra níbẹ̀, ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì.+ Ó wọ ilé kan níbẹ̀, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ nípa rẹ̀, síbẹ̀ àwọn èèyàn mọ̀.
6 gbogbo àwọn tó ń gbé agbègbè olókè láti Lẹ́bánónì+ lọ dé Misirefoti-máímù;+ àti gbogbo àwọn ọmọ Sídónì.+ Mo máa lé wọn kúrò* níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Kí o ṣáà rí i pé o pín in fún Ísírẹ́lì pé kó jẹ́ ogún wọn, bí mo ṣe pa á láṣẹ fún ọ.+
24 Ó gbéra níbẹ̀, ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì.+ Ó wọ ilé kan níbẹ̀, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ nípa rẹ̀, síbẹ̀ àwọn èèyàn mọ̀.