Jóṣúà 11:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà fi wọ́n lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́,+ wọ́n ṣẹ́gun wọn, wọ́n lé wọn títí dé Sídónì Ńlá+ àti Misirefoti-máímù+ àti Àfonífojì Mísípè lápá ìlà oòrùn, wọ́n sì pa wọ́n láìku ẹnì kankan.+
8 Jèhófà fi wọ́n lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́,+ wọ́n ṣẹ́gun wọn, wọ́n lé wọn títí dé Sídónì Ńlá+ àti Misirefoti-máímù+ àti Àfonífojì Mísípè lápá ìlà oòrùn, wọ́n sì pa wọ́n láìku ẹnì kankan.+