-
Jóṣúà 19:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 ó dé Ébúrónì, Réhóbù, Hámónì àti Kánà títí lọ dé Sídónì Ńlá.+
-
-
Jóṣúà 19:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Èyí ni ogún ẹ̀yà Áṣérì ní ìdílé-ìdílé.+ Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-