Jẹ́nẹ́sísì 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nígbà tí Ábúrámù ń pa dà bọ̀ lẹ́yìn tó ṣẹ́gun Kedoláómà àti àwọn ọba tó wà pẹ̀lú rẹ̀, ọba Sódómù jáde lọ pàdé Ábúrámù ní Àfonífojì* Ṣáfè, ìyẹn Àfonífojì Ọba.+
17 Nígbà tí Ábúrámù ń pa dà bọ̀ lẹ́yìn tó ṣẹ́gun Kedoláómà àti àwọn ọba tó wà pẹ̀lú rẹ̀, ọba Sódómù jáde lọ pàdé Ábúrámù ní Àfonífojì* Ṣáfè, ìyẹn Àfonífojì Ọba.+