Sáàmù 83:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+ Hébérù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, Kristi kọ́ ló ṣe ara rẹ̀ lógo + nígbà tó di àlùfáà àgbà, àmọ́ Ẹni tó sọ fún un pé: “Ìwọ ni ọmọ mi; òní ni mo di bàbá rẹ”+ ló ṣe é lógo. Hébérù 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 torí Ọlọ́run ti fi ṣe àlùfáà àgbà ní ọ̀nà ti Melikisédékì.+
18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+
5 Bákan náà, Kristi kọ́ ló ṣe ara rẹ̀ lógo + nígbà tó di àlùfáà àgbà, àmọ́ Ẹni tó sọ fún un pé: “Ìwọ ni ọmọ mi; òní ni mo di bàbá rẹ”+ ló ṣe é lógo.