ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 6:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mo ti máa ń fara han Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù pé èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè,+ àmọ́ ní ti orúkọ mi Jèhófà,+ mi ò jẹ́ kí wọ́n fi mọ̀ mí.+

  • Sáàmù 68:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ẹ kọrin sí Ọlọ́run; ẹ fi orin yin* orúkọ rẹ̀.+

      Ẹ kọrin sí Ẹni tó ń la àwọn aṣálẹ̀ tó tẹ́jú* kọjá.

      Jáà* ni orúkọ rẹ̀!+ Ẹ máa yọ̀ níwájú rẹ̀!

  • Àìsáyà 42:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;

      Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*

      Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+

  • Àìsáyà 54:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+

      Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,

      Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+

      Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́