Sáàmù 83:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+ Lúùkù 11:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí náà, ó sọ fún wọn pé: “Nígbàkigbà tí ẹ bá ń gbàdúrà, ẹ sọ pé: ‘Baba, kí orúkọ rẹ di mímọ́.*+ Kí ìjọba rẹ dé.+ Jòhánù 12:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Baba, ṣe orúkọ rẹ lógo.” Ni ohùn kan+ bá dún láti ọ̀run pé: “Mo ti ṣe é lógo, màá sì tún ṣe é lógo.”+ Ìṣe 15:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Símíónì+ ti ròyìn ní kíkún bí Ọlọ́run ṣe yí àfiyèsí rẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè fún ìgbà àkọ́kọ́ kí ó lè mú àwọn èèyàn kan jáde fún orúkọ rẹ̀ látinú wọn.+ Ìfihàn 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+
18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+
2 Torí náà, ó sọ fún wọn pé: “Nígbàkigbà tí ẹ bá ń gbàdúrà, ẹ sọ pé: ‘Baba, kí orúkọ rẹ di mímọ́.*+ Kí ìjọba rẹ dé.+
28 Baba, ṣe orúkọ rẹ lógo.” Ni ohùn kan+ bá dún láti ọ̀run pé: “Mo ti ṣe é lógo, màá sì tún ṣe é lógo.”+
14 Símíónì+ ti ròyìn ní kíkún bí Ọlọ́run ṣe yí àfiyèsí rẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè fún ìgbà àkọ́kọ́ kí ó lè mú àwọn èèyàn kan jáde fún orúkọ rẹ̀ látinú wọn.+
3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+