ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 10:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Orúkọ àwọn àpọ́sítélì méjìlá (12) náà nìyí:+ Àkọ́kọ́, Símónì, tí wọ́n ń pè ní Pétérù+ àti Áńdérù+ arákùnrin rẹ̀; Jémíìsì ọmọ Sébédè àti Jòhánù+ arákùnrin rẹ̀;

  • Ìṣe 11:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “Ó ròyìn fún wa bí ó ṣe rí áńgẹ́lì tó dúró ní ilé rẹ̀ tó sì sọ pé: ‘Rán àwọn èèyàn sí Jópà, kí o sì ní kí wọ́n pe Símónì tí wọ́n ń pè ní Pétérù wá,+

  • 2 Pétérù 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Símónì Pétérù, ẹrú àti àpọ́sítélì Jésù Kristi, sí ẹ̀yin tí ẹ ti ní irú ìgbàgbọ́ tó ṣeyebíye tí àwa náà ní,* nípasẹ̀ òdodo Ọlọ́run wa àti Jésù Kristi Olùgbàlà:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́