Jẹ́nẹ́sísì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+ Sáàmù 103:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí ó mọ ẹ̀dá wa,+Ó rántí pé erùpẹ̀ ni wá.+ Oníwàásù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ibì kan náà ni gbogbo wọn ń lọ.+ Inú erùpẹ̀ ni gbogbo wọn ti wá,+ inú erùpẹ̀ sì ni gbogbo wọn ń pa dà sí.+
19 Inú òógùn ojú rẹ ni wàá ti máa jẹun títí wàá fi pa dà sí ilẹ̀, torí inú rẹ̀ lo ti wá.+ Erùpẹ̀ ni ọ́, ìwọ yóò sì pa dà sí erùpẹ̀.”+
20 Ibì kan náà ni gbogbo wọn ń lọ.+ Inú erùpẹ̀ ni gbogbo wọn ti wá,+ inú erùpẹ̀ sì ni gbogbo wọn ń pa dà sí.+