ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jèhófà Ọlọ́run fi erùpẹ̀+ ilẹ̀ mọ ọkùnrin, ó mí èémí ìyè+ sí ihò imú rẹ̀, ọkùnrin náà sì di alààyè.*+

  • Jẹ́nẹ́sísì 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Jèhófà Ọlọ́run dá gbogbo ẹranko látinú ilẹ̀ àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, ó sì mú wọn wá sọ́dọ̀ ọkùnrin náà láti wo orúkọ tó máa sọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn; orúkọ tí ọkùnrin náà bá sì sọ ohun alààyè* kọ̀ọ̀kan ni wọ́n ń jẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́