Jẹ́nẹ́sísì 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà fi àjàkálẹ̀ àrùn* kọ lu Fáráò àti agbo ilé rẹ̀ nítorí Sáráì, ìyàwó Ábúrámù.+ Sáàmù 105:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kò gbà kí ẹnikẹ́ni ni wọ́n lára,+Ṣùgbọ́n nítorí wọn, ó bá àwọn ọba wí,+