-
Jẹ́nẹ́sísì 26:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Lẹ́yìn náà, Ábímélékì wá sọ́dọ̀ rẹ̀ láti Gérárì pẹ̀lú Áhúsátì agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ àti Fíkólì olórí àwọn ọmọ ogun+ rẹ̀.