Jẹ́nẹ́sísì 21:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Torí náà, wọ́n dá májẹ̀mú+ ní Bíá-ṣébà, lẹ́yìn náà, Ábímélékì àti Fíkólì olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbéra, wọ́n sì pa dà sí ilẹ̀ àwọn Filísínì.+
32 Torí náà, wọ́n dá májẹ̀mú+ ní Bíá-ṣébà, lẹ́yìn náà, Ábímélékì àti Fíkólì olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbéra, wọ́n sì pa dà sí ilẹ̀ àwọn Filísínì.+