Jẹ́nẹ́sísì 24:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ kí o lọ sí ilẹ̀ tí mo ti wá, lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí+ mi, kí o sì mú ìyàwó wá fún Ísákì ọmọ mi.”