ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 12:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́yìn náà, Ábúrámù kó kúrò níbẹ̀, ó sì gba ọ̀nà Négébù+ lọ, ó ń pa àgọ́ láti ibì kan dé ibòmíì.

  • Jẹ́nẹ́sísì 20:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ábúráhámù wá ṣí ibùdó rẹ̀ kúrò níbẹ̀+ lọ sí ilẹ̀ Négébù, ó sì ń gbé láàárín Kádéṣì+ àti Ṣúrì.+ Nígbà tó ń gbé* ní Gérárì,+

  • Nọ́ńbà 13:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì.

  • Àwọn Onídàájọ́ 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́yìn náà, àwọn ọkùnrin Júdà lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé agbègbè olókè jà, wọ́n tún bá Négébù àti Ṣẹ́fẹ́là+ jà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́