Jẹ́nẹ́sísì 36:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ísọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì: Ádà+ ọmọ Élónì ọmọ Hétì;+ Oholibámà+ ọmọ Ánáhì, ọmọ ọmọ Síbéónì ọmọ Hífì; 3 àti Básémátì+ ọmọ Íṣímáẹ́lì, arábìnrin Nébáótì.+ Àìsáyà 60:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 A máa kó gbogbo agbo ẹran Kídárì+ jọ sọ́dọ̀ rẹ. Àwọn àgbò Nébáótì+ máa sìn ọ́. Wọ́n máa wá sórí pẹpẹ mi pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà,+Màá sì ṣe ilé ológo mi* lọ́ṣọ̀ọ́.+
2 Ísọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì: Ádà+ ọmọ Élónì ọmọ Hétì;+ Oholibámà+ ọmọ Ánáhì, ọmọ ọmọ Síbéónì ọmọ Hífì; 3 àti Básémátì+ ọmọ Íṣímáẹ́lì, arábìnrin Nébáótì.+
7 A máa kó gbogbo agbo ẹran Kídárì+ jọ sọ́dọ̀ rẹ. Àwọn àgbò Nébáótì+ máa sìn ọ́. Wọ́n máa wá sórí pẹpẹ mi pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà,+Màá sì ṣe ilé ológo mi* lọ́ṣọ̀ọ́.+