1 Kíróníkà 1:29-31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ibi tí ìdílé wọn ti wá nìyí: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+ 30 Míṣímà, Dúmà, Máásà, Hádádì, Témà, 31 Jétúrì, Náfíṣì àti Kédémà. Àwọn yìí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì.
29 Ibi tí ìdílé wọn ti wá nìyí: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+ 30 Míṣímà, Dúmà, Máásà, Hádádì, Témà, 31 Jétúrì, Náfíṣì àti Kédémà. Àwọn yìí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì.