Jẹ́nẹ́sísì 27:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ló bá fèsì pé: “Abájọ tí orúkọ rẹ̀ fi ń jẹ́ Jékọ́bù,* ẹ̀ẹ̀mejì+ ló ti gba ipò mi báyìí! Ó ti kọ́kọ́ gba ogún ìbí mi,+ ó tún gba ìbùkún+ tó jẹ́ tèmi!” Ó wá sọ pé: “Ṣé o ò ṣẹ́ ìbùkún kankan kù fún mi ni?”
36 Ló bá fèsì pé: “Abájọ tí orúkọ rẹ̀ fi ń jẹ́ Jékọ́bù,* ẹ̀ẹ̀mejì+ ló ti gba ipò mi báyìí! Ó ti kọ́kọ́ gba ogún ìbí mi,+ ó tún gba ìbùkún+ tó jẹ́ tèmi!” Ó wá sọ pé: “Ṣé o ò ṣẹ́ ìbùkún kankan kù fún mi ni?”