Jẹ́nẹ́sísì 25:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lẹ́yìn náà, àbúrò rẹ̀ jáde, ó sì di gìgísẹ̀ Ísọ̀+ mú, torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Jékọ́bù.*+ Ẹni ọgọ́ta (60) ọdún ni Ísákì nígbà tí Rèbékà bí àwọn ọmọ náà. Jẹ́nẹ́sísì 32:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó wá sọ fún un pé: “O ò ní máa jẹ́ Jékọ́bù mọ́, Ísírẹ́lì*+ ni wàá máa jẹ́, torí o ti bá Ọlọ́run + àti èèyàn wọ̀jà, o sì ti wá borí.” Hósíà 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó wà nínú ìyá rẹ̀, ó gbá arákùnrin rẹ̀ mú ní gìgísẹ̀,+Ó sì fi gbogbo okun rẹ̀ bá Ọlọ́run wọ̀jà.+
26 Lẹ́yìn náà, àbúrò rẹ̀ jáde, ó sì di gìgísẹ̀ Ísọ̀+ mú, torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Jékọ́bù.*+ Ẹni ọgọ́ta (60) ọdún ni Ísákì nígbà tí Rèbékà bí àwọn ọmọ náà.
28 Ó wá sọ fún un pé: “O ò ní máa jẹ́ Jékọ́bù mọ́, Ísírẹ́lì*+ ni wàá máa jẹ́, torí o ti bá Ọlọ́run + àti èèyàn wọ̀jà, o sì ti wá borí.”
3 Nígbà tó wà nínú ìyá rẹ̀, ó gbá arákùnrin rẹ̀ mú ní gìgísẹ̀,+Ó sì fi gbogbo okun rẹ̀ bá Ọlọ́run wọ̀jà.+