Jẹ́nẹ́sísì 26:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ísákì tún àwọn kànga náà gbẹ́, ìyẹn àwọn kànga tí wọ́n gbẹ́ nígbà ayé Ábúráhámù bàbá rẹ̀ àmọ́ tí àwọn Filísínì dí pa lẹ́yìn ikú+ Ábúráhámù, ó sì pè wọ́n ní orúkọ tí bàbá rẹ̀ sọ wọ́n.+
18 Ísákì tún àwọn kànga náà gbẹ́, ìyẹn àwọn kànga tí wọ́n gbẹ́ nígbà ayé Ábúráhámù bàbá rẹ̀ àmọ́ tí àwọn Filísínì dí pa lẹ́yìn ikú+ Ábúráhámù, ó sì pè wọ́n ní orúkọ tí bàbá rẹ̀ sọ wọ́n.+