Hébérù 11:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ìgbàgbọ́ mú kí Ísákì náà súre fún Jékọ́bù+ àti Ísọ̀+ nípa àwọn ohun tó ń bọ̀.