-
Jẹ́nẹ́sísì 30:42, 43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Àmọ́ tí àwọn ẹran náà ò bá lókun, kò ní kó àwọn ọ̀pá náà síbẹ̀. Torí náà, àwọn tí kò lókun yẹn ló máa ń di ti Lábánì, àmọ́ àwọn tó sanra á di ti Jékọ́bù.+
43 Ohun ìní rẹ̀ wá ń pọ̀ sí i, ó ní agbo ẹran tó pọ̀ rẹpẹtẹ, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, ó sì tún ní àwọn ràkúnmí àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
-