-
Jẹ́nẹ́sísì 28:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jékọ́bù kúrò ní Bíá-ṣébà, ó sì ń lọ sí agbègbè Háránì.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 30:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Ohun ìní rẹ̀ wá ń pọ̀ sí i, ó ní agbo ẹran tó pọ̀ rẹpẹtẹ, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, ó sì tún ní àwọn ràkúnmí àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 32:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹ̀rù wá ba Jékọ́bù gan-an, ọkàn rẹ̀ ò sì balẹ̀.+ Torí náà, ó pín àwọn èèyàn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ àtàwọn agbo ẹran, àwọn màlúù àtàwọn ràkúnmí, ó pín wọn sí ọ̀nà méjì.
-