Àwọn Onídàájọ́ 13:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Mánóà wá sọ fún áńgẹ́lì Jèhófà pé: “Kí ni orúkọ rẹ,+ ká lè bọlá fún ọ tí ọ̀rọ̀ rẹ bá ṣẹ?” 18 Àmọ́ áńgẹ́lì Jèhófà sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń béèrè orúkọ mi, nígbà tí o rí i pé àgbàyanu ni?”
17 Mánóà wá sọ fún áńgẹ́lì Jèhófà pé: “Kí ni orúkọ rẹ,+ ká lè bọlá fún ọ tí ọ̀rọ̀ rẹ bá ṣẹ?” 18 Àmọ́ áńgẹ́lì Jèhófà sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń béèrè orúkọ mi, nígbà tí o rí i pé àgbàyanu ni?”