ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 32:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ni Jékọ́bù bá sọ pé: “Jọ̀ọ́, sọ orúkọ rẹ fún mi.” Àmọ́ ó fèsì pé: “Kí nìdí tí o fi ń béèrè orúkọ mi?”+ Ó sì súre fún un níbẹ̀.

  • Àwọn Onídàájọ́ 13:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Obìnrin náà wá lọ sọ fún ọkọ rẹ̀ pé: “Èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ kan wá sọ́dọ̀ mi, ó rí bí áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́, ó ń bani lẹ́rù gidigidi. Mi ò béèrè ibi tó ti wá lọ́wọ́ rẹ̀, kò sì sọ orúkọ rẹ̀ fún mi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́