Jẹ́nẹ́sísì 33:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jékọ́bù rìnrìn àjò wá láti Padani-árámù,+ ó sì dé sí ìlú Ṣékémù+ ní ilẹ̀ Kénáánì+ ní àlàáfíà, ó wá pàgọ́ sí tòsí ìlú náà. 19 Ó ra apá kan lára ilẹ̀ tó pa àgọ́ rẹ̀ sí lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hámórì, bàbá Ṣékémù, ó rà á ní ọgọ́rùn-ún (100) ẹyọ owó.+
18 Jékọ́bù rìnrìn àjò wá láti Padani-árámù,+ ó sì dé sí ìlú Ṣékémù+ ní ilẹ̀ Kénáánì+ ní àlàáfíà, ó wá pàgọ́ sí tòsí ìlú náà. 19 Ó ra apá kan lára ilẹ̀ tó pa àgọ́ rẹ̀ sí lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hámórì, bàbá Ṣékémù, ó rà á ní ọgọ́rùn-ún (100) ẹyọ owó.+