1 Kíróníkà 2:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ Júdà ni Éérì, Ónánì àti Ṣélà. Àwọn mẹ́ta yìí ni ọmọbìnrin Ṣúà ará Kénáánì+ bí fún un. Àmọ́, inú Jèhófà ò dùn sí Éérì àkọ́bí Júdà, torí náà Ó pa á.+ 4 Támárì+ ìyàwó ọmọ Júdà bí Pérésì+ àti Síírà fún un. Gbogbo àwọn ọmọ Júdà jẹ́ márùn-ún.
3 Àwọn ọmọ Júdà ni Éérì, Ónánì àti Ṣélà. Àwọn mẹ́ta yìí ni ọmọbìnrin Ṣúà ará Kénáánì+ bí fún un. Àmọ́, inú Jèhófà ò dùn sí Éérì àkọ́bí Júdà, torí náà Ó pa á.+ 4 Támárì+ ìyàwó ọmọ Júdà bí Pérésì+ àti Síírà fún un. Gbogbo àwọn ọmọ Júdà jẹ́ márùn-ún.