ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 2:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún,* ọba Íjíbítì kú,+ àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń kérora torí wọ́n wà lóko ẹrú, wọ́n sì ń ráhùn, igbe tí wọ́n ń ké fún ìrànlọ́wọ́ torí pé wọ́n ń fi wọ́n ṣe ẹrú sì dé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́.+

  • Ìṣe 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Yàtọ̀ síyẹn, Ọlọ́run sọ fún un pé àwọn ọmọ* rẹ̀ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n* fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́