-
Ẹ́kísódù 25:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n mú ọrẹ wá fún mi. Kí ẹ gba ọrẹ fún mi lọ́wọ́ gbogbo ẹni tí ọkàn rẹ̀ bá sún láti mú un wá.+
-