Ẹ́kísódù 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ẹ ṣe àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó máa wà níbẹ̀, kó rí bí ohun* tí màá fi hàn ọ́ gẹ́lẹ́.+ Ẹ́kísódù 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+
6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+