Ẹ́kísódù 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+
6 Bákan náà, mo ti yan Òhólíábù + ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì kó lè ràn án lọ́wọ́, màá sì fi ọgbọ́n sínú ọkàn gbogbo àwọn tó mọṣẹ́,* kí wọ́n lè ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ:+