ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Kí wọ́n fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àpótí, kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* méjì ààbọ̀, kí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀, kí gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+

  • Ẹ́kísódù 25:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “Kí o tún fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì,+ kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, kí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, kí gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+

  • Ẹ́kísódù 27:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “Kí o fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe pẹpẹ;+ kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* márùn-ún, kí fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún. Kí ẹ̀gbẹ́ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin pẹpẹ náà dọ́gba, kí gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta.+

  • Ẹ́kísódù 30:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Igi bọn-ọ̀n-ní ni kí o fi ṣe àwọn ọ̀pá náà, kí o sì fi wúrà bò wọ́n.

  • Ẹ́kísódù 36:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Lẹ́yìn náà, ó fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe òpó mẹ́rin fún un, ó sì fi wúrà bò wọ́n, pẹ̀lú àwọn ìkọ́ tó fi wúrà ṣe, ó sì fi fàdákà rọ ìtẹ́lẹ̀ mẹ́rin tó ní ihò fún wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́