Ẹ́kísódù 40:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí o gbé tábìlì+ náà wọlé, kí o sì to àwọn nǹkan tó yẹ kó wà lórí rẹ̀ síbẹ̀, kí o wá gbé ọ̀pá fìtílà+ wọlé, kí o sì tan àwọn fìtílà rẹ̀.+
4 Kí o gbé tábìlì+ náà wọlé, kí o sì to àwọn nǹkan tó yẹ kó wà lórí rẹ̀ síbẹ̀, kí o wá gbé ọ̀pá fìtílà+ wọlé, kí o sì tan àwọn fìtílà rẹ̀.+