-
Ẹ́kísódù 27:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Bàbà ni kí o fi ṣe gbogbo ohun èlò àti àwọn nǹkan tí ẹ ó máa fi ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìjọsìn náà, pẹ̀lú àwọn èèkàn àgọ́ náà àti gbogbo èèkàn àgbàlá náà.+
-