-
Ẹ́kísódù 38:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Bàbà ni wọ́n fi ṣe gbogbo èèkàn àgọ́ ìjọsìn náà àti àwọn tó wà yí ká àgbàlá náà.+
-
-
Nọ́ńbà 3:36, 37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Ojúṣe àwọn ọmọ Mérárì ni pé kí wọ́n máa bójú tó àwọn férémù+ àgọ́ ìjọsìn, àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀,+ àwọn òpó rẹ̀,+ àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀, gbogbo ohun èlò+ rẹ̀ àti gbogbo iṣẹ́ tó jẹ mọ́ nǹkan wọ̀nyí,+ 37 títí kan àwọn òpó tó yí àgbàlá náà ká àti àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò+ wọn, èèkàn àgọ́ wọn àti okùn àgọ́ wọn.
-