Ẹ́kísódù 36:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní+ ṣe àwọn férémù àgọ́ ìjọsìn náà, wọ́n sì wà ní òró.+