Ẹ́kísódù 36:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ó fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa tí wọ́n hun pọ̀ ṣe aṣọ* tí wọ́n máa ta sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà,+
37 Ó fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa tí wọ́n hun pọ̀ ṣe aṣọ* tí wọ́n máa ta sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà,+