-
Ẹ́kísódù 39:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Nígbà tí Mósè yẹ gbogbo iṣẹ́ tí wọ́n ṣe wò, ó rí i pé wọ́n ṣe é gẹ́lẹ́ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ; Mósè sì súre fún wọn.
-
-
Diutarónómì 4:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi kún ọ̀rọ̀ tí mò ń pa láṣẹ fún yín, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ yọ kúrò lára rẹ̀,+ kí ẹ lè máa tẹ̀ lé àwọn àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run yín tí mò ń pa láṣẹ fún yín.
-