ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 12:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Gbogbo ọ̀rọ̀ tí mò ń pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ rí i pé ẹ tẹ̀ lé.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi kún un, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ yọ kúrò nínú rẹ̀.+

  • Òwe 30:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mọ́.+

      Ó* jẹ́ apata fún àwọn tó ń wá ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀.+

       6 Má fi nǹkan kan kún ọ̀rọ̀ rẹ̀,+

      Nítorí á bá ọ wí,

      Wàá sì di òpùrọ́.

  • Ìfihàn 22:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Mò ń jẹ́rìí fún gbogbo ẹni tó ń gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ àkájọ ìwé yìí pé: Tí ẹnikẹ́ni bá fi kún àwọn nǹkan yìí,+ Ọlọ́run máa fi àwọn ìyọnu tó wà nínú àkájọ ìwé yìí kún un fún ẹni náà;+ 19 tí ẹnikẹ́ni bá sì yọ ohunkóhun kúrò nínú àwọn ọ̀rọ̀ àkájọ ìwé àsọtẹ́lẹ̀ yìí, Ọlọ́run máa yọ ìpín rẹ̀ kúrò nínú àwọn igi ìyè+ àti kúrò nínú ìlú mímọ́ náà,+ àwọn nǹkan tí a kọ nípa wọn sínú àkájọ ìwé yìí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́