Ẹ́kísódù 26:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Kí o tún fi irun ewúrẹ́+ ṣe àwọn aṣọ àgọ́ láti fi bo àgọ́ ìjọsìn náà. Kí o ṣe aṣọ àgọ́ mọ́kànlá (11).+
7 “Kí o tún fi irun ewúrẹ́+ ṣe àwọn aṣọ àgọ́ láti fi bo àgọ́ ìjọsìn náà. Kí o ṣe aṣọ àgọ́ mọ́kànlá (11).+