Ẹ́kísódù 37:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+ Hébérù 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí wọ́n kọ́ apá àkọ́kọ́ nínú àgọ́, níbi tí ọ̀pá fìtílà,+ tábìlì àti àwọn búrẹ́dì tí wọ́n ń gbé síwájú*+ wà; a sì ń pè é ní Ibi Mímọ́.+
10 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+
2 Torí wọ́n kọ́ apá àkọ́kọ́ nínú àgọ́, níbi tí ọ̀pá fìtílà,+ tábìlì àti àwọn búrẹ́dì tí wọ́n ń gbé síwájú*+ wà; a sì ń pè é ní Ibi Mímọ́.+